Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí alufaa yẹ̀ ẹ́ wò, bí wúwú tí ó wú yìí bá jìn ju awọ ara rẹ̀ lọ, tí irun rẹ̀ bá sì funfun; kí alufaa pè é ní aláìmọ́; àrùn ẹ̀tẹ̀ ni, ẹ̀tẹ̀ ni ó jẹ jáde gẹ́gẹ́ bí oówo.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:20 ni o tọ