Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ibìkan bá lé lára eniyan, tabi tí ara eniyan bá wú tí ọ̀gangan ibẹ̀ sì ń dán, tí ó bá jọ ẹ̀tẹ̀ ní ara rẹ̀, kí wọ́n mú olúwarẹ̀ tọ Aaroni, alufaa wá; tabi kí wọ́n mú un wá sí ọ̀dọ̀ ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Aaroni, tí ó jẹ́ alufaa.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:2 ni o tọ