Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 11:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohunkohun tí apákan ninu òkú wọn bá jábọ́ lé lórí di aláìmọ́, kì báà jẹ́ ààrò tabi àdògán, o gbọdọ̀ fọ́ ọ túútúú; wọ́n jẹ́ aláìmọ́, wọ́n sì gbọdọ̀ jẹ́ aláìmọ́ fun yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:35 ni o tọ