Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 11:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohunkohun tí ó bá jẹ́ jíjẹ tí ó bá wà ninu ìkòkò amọ̀ yìí, tabi tí omi inú rẹ̀ bá ta sí lára, di aláìmọ́, ohunkohun tí ó bá jẹ́ mímu, tí ó wà ninu rẹ̀ náà di aláìmọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:34 ni o tọ