Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá pe Miṣaeli ati Elisafani, àwọn ọmọ Usieli, arakunrin Aaroni, ó ní, “Ẹ lọ gbé òkú àwọn arakunrin yín kúrò níwájú ibi mímọ́, kí ẹ sì gbé wọn jáde kúrò láàrin ibùdó.”

Ka pipe ipin Lefitiku 10

Wo Lefitiku 10:4 ni o tọ