Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 9:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n lè ṣiṣẹ́ ní ilé Ọlọrun láìka àwọn eniyan wọn ati àwọn olórí ìdílé wọn gbogbo jẹ́ ẹgbẹsan ó dín ogoji (1,760).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:13 ni o tọ