Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 8:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Neri ni baba Kiṣi, Kiṣi ni ó bí Saulu, Saulu sì bí àwọn ọmọkunrin mẹrin: Jonatani, Malikiṣua, Abinadabu, ati Eṣibaali.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 8

Wo Kronika Kinni 8:33 ni o tọ