Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹran ọ̀sìn tí wọ́n kó lójú ogun nìwọ̀nyí: ẹgbaa mẹẹdọgbọn (50,000) ràkúnmí, ọ̀kẹ́ mejila lé ẹgbaarun (250,000) aguntan, ati ẹgbaa (2,000) kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́; wọ́n sì kó ọ̀kẹ́ marun-un (100,000) ọkunrin lẹ́rú.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 5

Wo Kronika Kinni 5:21 ni o tọ