Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 5:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n rí ìrànlọ́wọ́ gbà, wọ́n ṣẹgun àwọn ará Hagiriti ati àwọn tí wọ́n wà pẹlu wọn, nítorí wọ́n ké pe Ọlọrun lójú ogun náà, ó sì gbọ́ igbe wọn nítorí pé wọ́n gbẹ́kẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 5

Wo Kronika Kinni 5:20 ni o tọ