Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 29:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni àwọn olórí àwọn ìdílé, àwọn olórí àwọn ẹ̀yà Israẹli, àwọn ọ̀gágun ẹgbẹẹgbẹrun ọmọ ogun ati ti ọgọọgọrun-un ọmọ ogun, ati àwọn alabojuto ohun ìní ọba, bẹ̀rẹ̀ sí dá ọrẹ àtinúwá jọ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:6 ni o tọ