Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 29:5 BIBELI MIMỌ (BM)

ati àwọn ohun èlò mìíràn tí àwọn oníṣẹ́ ọnà yóo lò: wúrà fún àwọn ohun èlò wúrà, ati fadaka fún àwọn ohun èlò fadaka. Nisinsinyii, ninu yín, ta ló fẹ́ fi tinútinú ṣe ìtọrẹ, tí yóo sì ya ara rẹ̀ sọ́tọ̀ lónìí fún OLUWA?”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:5 ni o tọ