Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 29:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n jẹ, wọ́n sì mu níwájú Ọlọrun ní ọjọ́ náà pẹlu ayọ̀ ńlá.Wọ́n tún fi Solomoni, ọmọ Dafidi, jẹ ọba lẹẹkeji. Wọ́n fi òróró yàn án ní ọba ní orúkọ OLUWA, Sadoku sì ni alufaa.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:22 ni o tọ