Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 28:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi tún fún un ní ìwé ètò pípín àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi sí ìsọ̀rí-ìsọ̀rí, ati ètò gbogbo iṣẹ́ ìsìn inú ilé OLUWA, ti àwọn ohun èlò fún ìsìn ninu ilé OLUWA;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 28

Wo Kronika Kinni 28:13 ni o tọ