Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 28:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ati àwòrán gbogbo ohun tí ó ní lọ́kàn láti ṣe sinu àgbàlá ilé OLUWA, ati ti àwọn yàrá káàkiri, àwọn ilé ìṣúra tí yóo wà ninu ilé Ọlọrun, ati ti àwọn ilé ìṣúra tí wọ́n o máa kó ohun tí a yà sọ́tọ̀ fún OLUWA pamọ́ sí.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 28

Wo Kronika Kinni 28:12 ni o tọ