Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 26:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ìdílé Heburoni, Haṣabaya ati ẹẹdẹgbẹsan (1,700) àwọn arakunrin rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ alágbára ni wọ́n ń bojútó àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà ní apá ìwọ̀ oòrùn odò Jọdani, tí wọn ń ṣe iṣẹ́ OLUWA ati iṣẹ́ ọba,

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:30 ni o tọ