Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí gbogbo àwọn ọmọ Israẹli rí i bí iná ati ògo OLUWA ti sọ̀kalẹ̀ sórí tẹmpili, wọ́n dojúbolẹ̀, wọ́n sin Ọlọrun, wọ́n fi ọpẹ́ fún un, “Nítorí pé ó ṣeun, nítorí pé àánú rẹ̀ wà títí lae.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 7

Wo Kronika Keji 7:3 ni o tọ