Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní kí ẹ sọ ohun tí ẹ ti gbọ́ fún ọba Juda tí ó ranṣẹ láti wá wádìí lọ́wọ́ OLUWA Ọlọrun pé, èmi OLUWA Ọlọrun Israẹli ní,

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:26 ni o tọ