Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé wọ́n ti kọ òun OLUWA sílẹ̀, wọ́n sì ń sun turari sí àwọn oriṣa, kí wọ́n lè fi ìṣe wọn mú òun bínú; nítorí náà òun óo bínú sí ibí yìí, kò sí ẹni tí yóo lè dá ibinu òun dúró.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:25 ni o tọ