Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà fi òtítọ́ inú ṣe iṣẹ́ náà. Àwọn ọmọ Lefi tí wọn ń ṣàkóso wọn ni: Jahati ati Ọbadaya, láti inú ìran Merari, ati Sakaraya ati Meṣulamu, láti inú ìran Kohati. Àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n mọ̀ nípa ohun èlò orin

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:12 ni o tọ