Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sanwó fún àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà ati àwọn tí wọn ń mọlé, láti ra òkúta gbígbẹ́ ati pákó ati igi, kí wọ́n fi tún àwọn ilé tí àwọn ọba Juda ti sọ di àlàpà kọ́.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:11 ni o tọ