Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 32:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya náà ló dí ẹnu odò Gihoni ní apá òkè, ó ya omi rẹ̀ wọ ìhà ìwọ̀ oòrùn ìlú Dafidi. Hesekaya sì ń ní ìlọsíwájú ninu gbogbo iṣẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:30 ni o tọ