Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 30:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá pada sọ́dọ̀ OLUWA, àwọn arakunrin yín ati àwọn ọmọ yín yóo rí àánú lọ́dọ̀ àwọn tí ó kó wọn lẹ́rú, wọn yóo sì dá wọn pada sí ilẹ̀ yìí. Nítorí olóore ọ̀fẹ́ ati aláàánú ni OLUWA Ọlọrun yín, kò ní kẹ̀yìn si yín bí ẹ bá pada sọ́dọ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:9 ni o tọ