Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 30:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe oríkunkun, bí àwọn baba yín. Ẹ fi ara yín fún OLUWA, kí ẹ wá sí ibi mímọ́ rẹ̀, tí ó ti yà sọ́tọ̀ títí lae. Ẹ wá sin OLUWA Ọlọrun yín níbẹ̀, kí ibinu rẹ̀ lè yipada kúrò lọ́dọ̀ yín.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:8 ni o tọ