Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 29:6 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí àwọn baba wa ti ṣe aiṣododo, wọ́n sì ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA, Ọlọrun wa. Wọ́n kọ OLUWA sílẹ̀, wọ́n gbójú kúrò lára ibùgbé rẹ̀, wọ́n sì kẹ̀yìn sí i.

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:6 ni o tọ