Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 29:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọmọ Lefi, ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì ya ilé OLUWA, Ọlọrun àwọn baba yín sí mímọ́ pẹlu. Ẹ kó gbogbo àwọn nǹkan ẹ̀gbin kúrò ninu ibi mímọ́,

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:5 ni o tọ