Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 29:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn akọ mààlúù ni wọ́n kọ́kọ́ pa, àwọn alufaa gba ẹ̀jẹ̀ wọn, wọ́n dà á sára pẹpẹ. Lẹ́yìn náà wọ́n pa àwọn àgbò, wọ́n sì da ẹ̀jẹ̀ wọn sára pẹpẹ.

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:22 ni o tọ