Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 29:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi akọ mààlúù meje, àgbò meje, ọ̀dọ́ aguntan meje ati òbúkọ meje rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ìjọba Hesekaya, ati ilé OLUWA ati ilé Juda. Ọba pàṣẹ pé kí àwọn alufaa, àwọn ọmọ Aaroni, fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:21 ni o tọ