Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 27:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yòókù tí Jotamu ṣe ati àwọn ogun tí ó jà, ati àwọn nǹkan mìíràn tí ó tún ṣe ni a kọ sinu ìwé àwọn ọba Israẹli ati ti Juda.

Ka pipe ipin Kronika Keji 27

Wo Kronika Keji 27:7 ni o tọ