Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 27:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ohun tí ó tọ́ lójú OLUWA, gẹ́gẹ́ bíi Usaya, baba rẹ̀; àfi pé òun kò lọ sun turari ninu tẹmpili OLUWA. Ṣugbọn àwọn eniyan ń bá ìwà burúkú wọn lọ.

Ka pipe ipin Kronika Keji 27

Wo Kronika Keji 27:2 ni o tọ