Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 27:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni Jotamu nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹrindinlogun. Jeruṣa, ọmọ Sadoku ni ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 27

Wo Kronika Keji 27:1 ni o tọ