Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 26:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Usaya ọba di adẹ́tẹ̀ títí ọjọ́ ikú rẹ̀. Ọ̀tọ̀ ni wọ́n kọ́ ilé fún un tí ó ń dá gbé; nítorí wọ́n yọ ọ́ kúrò ninu ilé OLUWA. Jotamu ọmọ rẹ̀ di alákòóso ìjọba, ó sì ń darí àwọn ará ìlú.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:21 ni o tọ