Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 26:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Asaraya, olórí alufaa ati àwọn alufaa rí i tí ẹ̀tẹ̀ yọ níwájú rẹ̀, wọ́n yára tì í jáde. Ìkánjú ni òun pàápàá tilẹ̀ bá jáde, nítorí pé OLUWA ti jẹ ẹ́ níyà.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:20 ni o tọ