Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 23:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún keje Jehoiada alufaa mọ́kàn gírí, ó lọ bá àwọn marun-un ninu àwọn balogun dá majẹmu. Àwọn ni: Asaraya, ọmọ Jerohamu, Iṣimaeli ọmọ Jehohanani, Asaraya ọmọ Obedi, Maaseaya ọmọ Adaya ati Eliṣafati ọmọ Sikiri.

Ka pipe ipin Kronika Keji 23

Wo Kronika Keji 23:1 ni o tọ