Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 21:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mejilelọgbọn ni nígbà tí ó gorí oyè, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹjọ. Nígbà tí ó kú, kò sí ẹni tí ó sọkún, tabi tí ó ṣọ̀fọ̀ níbi òkú rẹ̀. Ìlú Dafidi ni wọ́n sin ín sí, ṣugbọn kì í ṣe ní ibojì àwọn ọba.

Ka pipe ipin Kronika Keji 21

Wo Kronika Keji 21:20 ni o tọ