Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 21:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọdún keji tí àìsàn náà tí ń ṣe é, ìfun rẹ̀ tú síta, ó sì kú ninu ọpọlọpọ ìrora. Wọn kò dá iná ẹ̀yẹ fún un gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti máa ń ṣe níbi ìsìnkú àwọn baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 21

Wo Kronika Keji 21:19 ni o tọ