Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 20:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoṣafati jọba lórí Juda, ẹni ọdún marundinlogoji ni nígbà tí ó gorí oyè. Gbogbo ọdún tí ó lò lórí oyè jẹ́ ọdún mẹẹdọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Asuba, ọmọ Ṣilihi.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:31 ni o tọ