Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 16:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ojú OLUWA ń lọ síwá sẹ́yìn ní gbogbo ayé láti fi agbára rẹ̀ hàn fún àwọn tí wọ́n jẹ́ olóòótọ́ sí i. Ìwà òmùgọ̀ ni èyí tí o hù yìí; nítorí pé láti ìsinsìnyìí lọ nígbàkúùgbà ni o óo máa jagun.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 16

Wo Kronika Keji 16:9 ni o tọ