Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 16:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí ogun Etiopia ati Libia lágbára gidigidi? Ṣebí wọ́n ní ọpọlọpọ kẹ̀kẹ́ ogun ati ẹlẹ́ṣin? Ṣugbọn nítorí pé o gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, ó fún ọ ní ìṣẹ́gun lórí wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 16

Wo Kronika Keji 16:8 ni o tọ