Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli rí i pé Rehoboamu kò gbọ́ tiwọn, wọ́n dáhùn pé,“Kí ló kàn wá pẹlu ilé Dafidi?Kí ló pa wá pọ̀ pẹlu ọmọ Jese?Ẹ pada sinu àgọ́ yín, ẹ̀yin ọmọ IsraẹliDafidi, fọwọ́ mú ilé rẹ.”Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá pada lọ sí ilé wọn,

Ka pipe ipin Kronika Keji 10

Wo Kronika Keji 10:16 ni o tọ