Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fun Joṣua pé, “Na ọ̀kọ̀ tí ó wà ní ọwọ́ rẹ sí ọ̀kánkán Ai, nítorí n óo fi lé ọ lọ́wọ́.” Joṣua bá na ọ̀kọ̀ ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀kánkán ìlú náà.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:18 ni o tọ