Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 8:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sì sí ẹyọ ọkunrin kan tí ó kù ní Ai ati Bẹtẹli tí kò jáde láti lépa àwọn ọmọ Israẹli. Wọ́n fi ìlẹ̀kùn ẹnubodè sílẹ̀ ní ṣíṣí, wọ́n ń lé àwọn ọmọ Israẹli lọ.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:17 ni o tọ