Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ bá a lọ títí wọ́n fi fẹ́rẹ̀ dé ìlú Ai, wọ́n sì pàgọ́ wọn sí apá ìhà àríwá ìlú náà, odò kan ni ó wà láàrin wọn ati ìlú Ai.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:11 ni o tọ