Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua dìde ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́ keji, ó pe gbogbo àwọn eniyan náà jọ. Òun ati àwọn àgbààgbà Israẹli ṣáájú wọn, wọ́n lọ sí Ai.

Ka pipe ipin Joṣua 8

Wo Joṣua 8:10 ni o tọ