Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí Giligali, wọ́n ṣe àjọ̀dún àjọ ìrékọjá ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrinla oṣù náà, ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹriko.

Ka pipe ipin Joṣua 5

Wo Joṣua 5:10 ni o tọ