Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kinni ni àwọn eniyan náà gun òkè odò Jọdani. Wọ́n pàgọ́ sí Giligali ní ìhà ìlà oòrùn Jẹriko.

Ka pipe ipin Joṣua 4

Wo Joṣua 4:19 ni o tọ