Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Majẹmu OLUWA jáde kúrò ninu odò Jọdani, bí wọ́n ti ń gbé ẹsẹ̀ lé ilẹ̀ gbígbẹ, ni omi odò náà pada sí ààyè rẹ̀. Odò náà sì kún bo gbogbo bèbè rẹ̀, bí ó ti wà tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 4

Wo Joṣua 4:18 ni o tọ