Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ máa kó ọpọlọpọ dúkìá pada lọ sí ilé yín, ati ọpọlọpọ ẹran ọ̀sìn, fadaka, wúrà, idẹ, irin, ati ọpọlọpọ aṣọ. Ẹ pín ninu ìkógun tí ẹ kó lọ́dọ̀ àwọn ọ̀tá yín fún àwọn arakunrin yín.”

Ka pipe ipin Joṣua 22

Wo Joṣua 22:8 ni o tọ