Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 20:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òdìkejì odò Jọdani, ní apá ìlà oòrùn Jẹriko, wọ́n ya Beseri tí ó wà ninu aṣálẹ̀ ní ilẹ̀ tí ó tẹ́jú sọ́tọ̀. Wọ́n ya Ramoti tí ó wà ní Gileadi sọ́tọ̀ ní agbègbè ti ẹ̀yà Gadi, ati Golani tí ó wà ní Baṣani, ní agbègbè ti ẹ̀yà Manase.

Ka pipe ipin Joṣua 20

Wo Joṣua 20:8 ni o tọ