Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 20:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ya Kedeṣi sọ́tọ̀ ní Galili ní agbègbè olókè ti Nafutali, ati Ṣekemu ní agbègbè olókè ti Efuraimu, ati Kiriati Ariba (tí wọ́n ń pè ní Heburoni), ní agbègbè olókè ti Juda.

Ka pipe ipin Joṣua 20

Wo Joṣua 20:7 ni o tọ