Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ààlà ilẹ̀ tí wọ́n pín fún àwọn ọmọ Josẹfu bẹ̀rẹ̀ láti odò Jọdani lẹ́bàá Jẹriko, ní apá ìlà oòrùn àwọn odò Jẹriko, ó lọ títí dé apá aṣálẹ̀. Ó tún bẹ̀rẹ̀ láti Jẹriko lọ sí apá àwọn ìlú tí ó wà ní orí òkè, títí dé Bẹtẹli.

Ka pipe ipin Joṣua 16

Wo Joṣua 16:1 ni o tọ